tọ́lá

verb
tọ́-lá | \ \ | IBADAN |

Definition of tọ́lá 

1 : Kí èèyàn pọ́n nǹkan lá. Kí èèyàn fi ahọ́n lá nǹkan.:

2 : Orúkọ èèyàn [See: "Tọ́lá" on YorubaName.com]:

English Translation

To lick (something). Personal name: Tọ́lá

Morphology

tọ́-lá

Gloss

tọ́ - [merely descriptive]

lá - lick

Variants

  • Pọ́nlá or Pọ́n lá
  • lá

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 10 Jun 2018

Most Popular