Oops! No match found for lá
Would you like to submit the word to our database? Kindly go to the word submission page.

Find below names that could be similar


àbẹ́là

Brief Meaning: Ohun kan tó ń mú iná wá nígbà tí a bá ṣáná sí i lórí


adúláwọ̀

Brief Meaning: Ẹni tí ó dúdú


àlà

Brief Meaning: Irúfẹ́ aṣọ funfun kan


aláboyún

Brief Meaning: Ẹni tó lóyún.


alágbádá

Brief Meaning: Ẹni tó ní agbádá, tàbí ẹni tó ń wọ agbádá


alágbẹ̀dẹ

Brief Meaning: Ẹni tó ń rọ irin.


ìmúláradá

Brief Meaning: Ìlànà mímú ènìyàn tàbí ohun kan padà sí ipò ìlera tàbí ipò tó dára lẹ́yìn àìsàn, ìpalára, ìbàjẹ́, tàbí ìṣòro.


olùgbàlà

Brief Meaning: Ẹni tí ó gba ẹlòmíràn lọ́wọ́ ewu, ìpọ́njú, tàbí ìparun.


tọ́lá

Brief Meaning: Kí èèyàn pọ́n nǹkan lá. Kí èèyàn fi ahọ́n lá nǹkan.