1: Eléyìí ni ẹ̀rọ tó máa ń fẹ́ atẹ́gùn sínú ilé láti fi tutù nítorí ooru.:
Air condition
f.a.:Mo fẹ́ràn láti máa sùn sínú yàrá tó bá ní ẹ̀rọ-amúlétutù nínú.
I love to sleep inside room that has air condition.
Morphology
ẹ̀rọ-amú-ilé-tutù
Gloss
ẹ̀rọ - machine, device, technology
amú - that make
ilé - house, home
tutù - cold
What Do You Think About This Word?
How could we have illustrated it better?
Updated on November 06, 2026
and
Submitted on November 05, 2026