àsedànù

Noun
à-se-dà-nù | | GENERAL |

Definition of àsedànù 

1 : Ìmúṣẹ iṣẹ́, akitiyan, tàbí làálàá tí kò mú èso rere jáde, tó já sí òfò tàbí asán kòkòrò.: wasted effort; unprofitable labour; futile enterprise. f.a.: Olúwa, má jẹ́ kí n ṣe iṣẹ́ àṣedànù lórí àwọn ọmọ mi. Lord, do not let me experience wasted effort over my children. f.a.: Ẹni tí ò bá fẹ́ ṣe àṣedànù, kò leè ṣe àṣejèrè. Whoever is unwilling to risk a loss or failure cannot experience profit or success.

2 : Nǹkan ìní tàbí ohun rere tí ènìyàn fúnni tó padà di nǹkan kòbákòá tàbí tí ẹni tí a ṣe lọ́re rẹ̀ kò mọ rírì rẹ̀.: unappreciated benevolence; a wasteful or unrewarded spending of resources. f.a.: Bí àṣedànù ò bá ní í pọ̀, ẹni a ṣoore fún ò ní mọ̀ ọ́. Unless the spending (or loss) is significant, the recipient of one's benevolence will not fully appreciate f.a.: Owó tí mo fi rán ọmọ ọ̀bọ yẹn ní ilé-ìwé jẹ́ àṣedànù nítorí ó sá kúrò níbẹ̀. The money I spent sending that rebellious child to school was a total waste because he dropped out.

Morphology

à-se-dà-nù

Gloss

à - the act of

se - do

dà - pour, spread

nù - lost

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 06, 2026 and Submitted on November 05, 2026