yunra

Verb
yun-ra | | GENERAL |

Definition of yunra 

1 : Láti má lè gba ohunkóhun tàbí fẹ́ ohunkóhun.: picky f.a.: Dùnmínínú máa ń yunra gan. Dunmininu is very picky.

Morphology

yùn-ara

Gloss

yùn - crave, seek after

ara - body, bodies

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 06, 2026 and Submitted on November 06, 2026