1 : Ohun tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe, tàbí tí a ṣẹ̀sẹ̀ s’ẹ̀dá, tí ẹnikẹ́ni kò tíì lò. Ó tún le jẹ́ nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ fún ìgbà àkọ́kọ́: new f.a.: Asọ tuntun ni màá wọ̀ fún ọdún kérésì I will be wearing a new cloth for christmas
Most Popular