1 Ilẹ̀ tàbí agbègbè kan tí àwọn ènìyàn ń gbé, tí ó sì ní ìjọba àti ètò ìṣàkóso tirẹ̀. Ó lè ní àwọn ènìyàn tí wọ́n ní èdè, àṣà, ìtàn, àti ìdánimọ̀ orílẹ̀-èdè kan náà. A geographical and political territory inhabited by a population and governed through an established system of administration. Its people may share a common language, culture, history, or national identity. f.a.: Nàìjíríà jẹ́ orílẹ̀-èdè kan ní Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà. Nigeria is a country in West Africa.
Most Popular