1: Ẹni tí ó ṣẹ́gun nínú gbogbo àwọn ẹni tí wọ́n jọ kópa nínú nǹkan ọ̀hún.:
conqueror, winner, victor
f.a.:Déolú ni ó jáwẹ́ olúborí láàrin àwọn tí wọ́n sáré ìdíje náà.
Déolú emerged as the winner in the race competition.
Morphology
ẹni-ì-borí
Gloss
ẹni - person
ì - something that
borí - to win, to conquer, to overcome, to defeat
What Do You Think About This Word?
How could we have illustrated it better?
Updated on November 06, 2026
and
Submitted on November 05, 2026