olùborí

Noun
o-lù-bo-rí | | GENERAL |

Definition of olùborí 

1 : Ẹni tí ó ṣẹ́gun nínú gbogbo àwọn ẹni tí wọ́n jọ kópa nínú nǹkan ọ̀hún.: conqueror, winner, victor f.a.: Déolú ni ó jáwẹ́ olúborí láàrin àwọn tí wọ́n sáré ìdíje náà. Déolú emerged as the winner in the race competition.

Morphology

ẹni-ì-borí

Gloss

ẹni - person

ì - something that

borí - to win, to conquer, to overcome, to defeat

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 06, 2026 and Submitted on November 05, 2026