ilé-ẹ̀kọ́

Noun
i-lé-ẹ̀-kọ́ | | GENERAL |

Definition of ilé-ẹ̀kọ́ 

1 : Ibi tí ó wà fún kíkọ́ àti mímọ̀ láti ní òye, ọgbọ́n: School f.a.: Ilé-ẹ̀kọ́ àgbà ti bẹ̀rẹ̀ ní iléẹ̀kọ́ tí ó wà ní ẹ̀gbẹ́ àfin ọba. Adult learning classes has started in the school beside the palace.

Morphology

ilé-ẹ̀kọ́

Gloss

ilé - house/home

ẹ̀kọ́ - education/learning

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 15, 2026 and Submitted on November 03, 2026