ilé-ìwòsàn

Noun
i-lé-ì-wò-sàn | | Formal |

Definition of ilé-ìwòsàn 

1 Ilé ńlá tàbí ibi pàtàkì tí a kọ́ fún títọ́jú àwọn aláìsàn, ṣíṣe àyẹ̀wò ìlera, àti fífúnni ní oògùn lábẹ́ ìṣàkóso àwọn dókítà àti nọ́ọ̀sì; ọsibítù. A hospital; a clinic; f.a.: Wọ́n tí gbé Adéwálé lọ Ilé-ìwòsàn Adéwàlé was taken to the hospital. f.a.: Àwọn òbí ọmọdé náà gbé e lọ sí ilé-ìwòsàn nígbà tí ibà rẹ̀ gbóná jù. The child's parents took him to the hospital when his fever became too high.

2 Ibùdó ìtọ́jú níbi tí àwọn oníṣègùn ìbílẹ̀ tàbí eléwé-ọmọ ń tọ́jú àwọn aláìsàn pẹ̀lú ewé àti egbòogi. A traditional healing home or herbal clinic. f.a.: Bàbá oníṣègùn náà ṣí ilé-ìwòsàn ìbílẹ̀ rẹ̀ sí ẹ̀bá odò ní ìlú wa. The traditional healer opened his indigenous clinic near the river in our town.

Morphology

ilé-ì-wò-ṣàn

Gloss

ilé - house, home

ì - something that

wò - nurse

ṣàn - heal

Variants

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 27, 2026 and Submitted on November 16, 2026