1 : Ilé tí àwọn èèyàn ti máa ń lọ láti lọ jayẹ́, gbafẹ́, gba fàájì tàbí sinmi.: hotel f.a.: Ilé-ìtura ni mo máa sùn ní ọ̀la nígbà tí mo bá dé ìlú Ìbàdàn. I will sleep in a hotel tomorrow when I get to Ibadan
ilé-ìtu-ara
ilé - house, home
ìtu - relax
ara - body
How could we have illustrated it better?
Most Popular