ìrànlọ́wọ́

noun
ì-ràn-lọ́-wọ́ | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of ìrànlọ́wọ́ 

1 : Oun tí a ṣe fún ènìyàn mìíràn, tó mú iṣẹ́ tàbí ayée wọn rọrùn.:

2 : Ṣe ìrànlọ́wọ́ fún mi.:

English Translation

Assistance. Help. Help me.

Morphology

ì-rànlọ́wọ́

Gloss

- the act of

rànlọ́wọ́ - help (verb)

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 18 Nov 2019

Most Popular