1 : Iṣẹ́ ìkà iye àwọn ènìyàn tó ń gbé ní orílẹ̀-èdè tàbí agbègbè kan ní àkókò pàtó kan.: census, population census f.a.: Ìjọba kéde pé ètò ìkàníyàn tuntun yóò wáyé lọ́dún tó ń bọ̀. The government announced that a new census would take place next year.
Most Popular