gbéraga

verb
gbé-ra-ga | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of gbéraga 

1 : Kí èèyàn rí ara rẹ̀ bí ẹni tó dára ju gbogbo ènìyàn yòókù lọ.:

English Translation

To be proud.

Morphology

gbé-ara-ga

Gloss

gbé - carry

ara - body

ga - up, high, tall

Variants

  • Gapá

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 05 Dec 2019

Most Popular