fàwọ̀rajà

noun
fà-wọ̀-a-jà | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of fàwọ̀rajà 

1 : Ẹni tó máa ń rí ojú rẹre gbà nítorí ẹwà rẹ̀ nìkan. [Èébú]: Ọjọ́ gbogbo fún fàwọ̀rajà, ọjọ́ kan fún ìyàwó ilé.

English Translation

A person that gets favours from others by taking advantage of their physical beauty

Morphology

fi-àwọ̀-ra-ọjà

Gloss

fi - use

àwọ̀ - skin/flesh

ra - buy

ọjà - goods

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 20 Nov 2018

Most Popular