ẹlẹ́wọ̀n

Noun
ẹ-lẹ́-wọ̀n | ɛlɛ́wɔ̀̃ | GENERAL |

Definition of ẹlẹ́wọ̀n 

1 : Ẹni tá a fi sínú àtìmọ́lé tàbí tí ìjọba ti fi sí àhámọ́ nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n ṣẹ̀: prisoner f.a.: Ẹlẹ́wọ̀n ò ní òmìnira kankan A prisoner has no freedom at all

Morphology

oní-ẹ̀wọ̀n

Gloss

oní - one who

ẹ̀wọ̀n - chain, prison

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 08, 2026 and Submitted on November 05, 2026