èsì

noun

Definition of èsì 

1 : Oun tí a sọ tàbí kọ gẹ́gẹ́ bí ìdáhùn sí ìbéèrè tàbí ọ̀rọ̀ míràn.: "Ìsọ̀rọ̀ ni ìgb'èsì" - Òwe Yorùbá

2 : Oun tí a rí gbà gẹ́gẹ́ bíi àtubọ̀tán oun tí a ṣe.: Mo ti rí èsì ìdánwò tí mo kọ.

English Translation

A response. A reply. Results.

Morphology

èsì

Gloss

èsì - A response

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 03 Dec 2019

Most Popular