ayédèrú

noun
a-yé-dè-èrú | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of ayédèrú 

1 : Ohun tó yàtọ̀ sí èyí tó jẹ́ gidi tàbí òótọ́.: Ayédèrú oyin ti pọ̀ níta.

English Translation

Fake, counterfeit.

Morphology

ayé-di-èrú

Gloss

ayé - The world, life, people (of the world)

di - become, turned to

èrú - fake, contraband, counterfeit, deceptive

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 05 Dec 2019

Most Popular