akọgun

noun
a-kọ-gun | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of akọgun 

1 : Akíkanjú ènìyàn tí a máa ń pè láti ṣáájú tí ogun tàbí ìjọ̀gbọ̀n bá bẹ́ sílẹ̀.:

English Translation

Warrior.

Morphology

a-kọ̀-ogun

Gloss

a - someone (ènìyàn)

kọ̀ - reject

ogun - war

Variants

  • Akíkanjú

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 25 Nov 2019

Most Popular