agbófinró

noun
a-gbó-fin-ró | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of agbófinró 

1 : Ẹni tí òfin ìlú tàbí ẹgbẹ́ yàn láti rí dájú pé àwọn èèyàn ń tẹ́lẹ̀ òfin tàbí ìlànà.: Àwọn agbófinró ojú pópó ń gbìyànjú.

English Translation

Law enforcement official.

Morphology

a-gbé-òfin-ro

Gloss

a - Person

gbé-ró - carry, uphold, enfoce

òfin - Law, rules

-

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 04 Dec 2019

Most Popular