1 : Ẹni ti awon eeyan gbagbo wipe ó wà láàyè níbi meji ọ̀tọ̀tọ̀ sùgbọ́n ní àkókò kan náà, tí ó sì lè farahàn ní ìrísí ènìyàn ní àwọn ibi méjèèjì..: Reincarnated person f.a.: Ìtàn àbaraméjì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbàgbọ́ àṣà ìbílẹ̀ Yorùbá. The story of abaraméjì is one of the beliefs in traditional Yoruba culture.
Most Popular