àkọsílẹ̀

Noun
à-kọ-sí-lẹ̀ | | GENERAL |

Definition of àkọsílẹ̀ 

1 : Ohun tí a kọ láti fi pamọ́ fún ìrántí, ẹ̀rí, tàbí ìtọ́kasí ní ọjọ́ iwájú: record, documentation f.a.: Ilé-iṣẹ́ náà ń pa àkọsílẹ̀ àwọn ìnáwó rẹ̀ mọ́. The organisation keeps a record of its expenses.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 13, 2026 and Submitted on November 13, 2026