Ìjọ

noun

Definition of Ìjọ 

1 : Ìpéjọpọ̀ àwọn ènìyàn tó ní àfojúsùn kan.: Ìjọ àwọn òǹkọ́wé.

2 : Ìpéjọpọ̀ ẹ̀sìn.: 1. Ṣé o ti sìn ní ìjọ ọ̀rúnmìlà rí? 2. Ìjọ Kérúbù ni wọ́n ń lọ.

English Translation

A conference/gathering. A religious gathering.

Morphology

Ì-jọ

Gloss

Ì - The act of

jọ - Gathering

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 03 Dec 2019 and Submitted on 03 Dec 2019

Most Popular