Èédú

noun
è-é-dú | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of Èédú 

1 : Ohun dúdú tí à rí láti ara igi jíjó, tí a máa ń lò láti dáná.: Lọ bu èédú wá.

English Translation

Charcoal

Morphology

èé-dú

Gloss

èé - [something carrying the characteristics of...]

dú - a shortened form of 'black' (dúdú)

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 01 Dec 2019 and Submitted on 28 Nov 2019

Most Popular