Èébú

noun
è-é-bú | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of Èébú 

1 : Ìsọ̀rọ̀sí l'ọ́nà òdì. Oun tí a sọ láti fi bú èèyàn.: "Èébú àlọ ni ti abahun, ti ààbọ̀ ni ti àna ẹ̀."

English Translation

An insult.

Morphology

èé-bú

Gloss

èé - [something]

bú - insult, berate

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 03 Dec 2019 and Submitted on 28 Nov 2019

Most Popular