Adájọ́

noun

Definition of Adájọ́ 

1 : Ẹni tí ó jẹ́ amòfin tí a yàn láti yanjú ìjà tàbí ìkùnsínú láàrín àwọn èèyàn tàbí ẹgbẹ́.: Amòfin Tolú ni adájọ́ àgbà tuntun fún Ìpínlẹ̀ wa

English Translation

A person of the law who is appointed to settle conflicts or misunderstanding among people or groups.

Morphology

a-dá-ẹjọ́

Gloss

a - someone, person

dá - create, render

ẹjọ́ - case, judgment

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 03 Dec 2019 and Submitted on 21 Nov 2019

Most Popular