ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́

noun
ọ̀-tẹ-lẹ̀-mú-yẹ́ | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ 

1 : Ènìyàn oníṣẹ́ ààbò ìlú (bíi ọlọ́pàá) tí kìí wọ'ṣọ ìdánimọ̀.: Àwọn ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ ti lọ sí àdúgbò tí olè ti jà lánàá.

English Translation

Detective. Any undercover security person/team.

Morphology

ọ̀-tẹ-ilẹ̀-múyẹ́

Gloss

ọ̀ - someone

tẹ - tread

ilẹ̀ - ground, floor, earth

múyẹ́ - gently, quietly

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 07 Dec 2019

Most Popular