Ọjà

noun

Definition of Ọjà 

1 : Àyè ìta gbangba tí a yà sọ́tọ̀ láti ra ǹkan tàbí ta ǹkan.: Ọjà Bódìjà ni mo ti ra ẹran.

2 : Àwọn ẹrù tí èèyàn fẹ́ tà.: Ọjà yẹn wọ́n.

English Translation

An open place designated for buying and selling. Goods one want to sell.

Morphology

ọjà

Gloss

ọjà - market

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 03 Dec 2019 and Submitted on 03 Dec 2019

Most Popular