ẹ̀fọ́rí

noun
ẹ̀-fọ́-rí | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of ẹ̀fọ́rí 

1 : Oríṣi àìsàn kan tí ó máa ń mú kí orí fọ́, dùn tàbí ro èèyàn.: 1. "Orí bíbẹ́ kọ́ l'oògù orí fífọ́ (ẹ̀fọ́rí)." Òwe 2. Dókítà ti fún mi ní oògùn fún ẹ̀fọ́rí mi.

English Translation

An headache.

Morphology

ẹ̀-fọ́-orí

Gloss

ẹ̀ - the act of

fọ́ - break, pound

orí - head

Variants

  • Ori fífọ́

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 03 Dec 2019

Most Popular