1 : Ẹni tí kò ní òye, ọgbọ́n, tàbí ìronú jinlẹ̀; ẹni tí ó máa ń hùwà àìnílàákàyè tàbí tí kò lè fojú inú wo ìyọrísí ìṣe rẹ̀; apọ̀dà.: A fool; an idiot; a simpleton; stupid person f.a.: Òmùgọ̀ ni gbogbo èèyàn ń pè mí nígbà tí wọ́n gbọ́. Everyone was calling me a fool when they heard.
2 : Ẹni tí ó rọrùn láti tàn jẹ tàbí tí kò mọ nǹkan tí ó ń lọ ní àyíká rẹ̀; òpè.: A gullible person; a naive or clueless individual f.a.: Àwọn oníjìbìtì náà rò pé òmùgọ̀ ni bàbá àgbàlagbà yẹn, ṣùgbọ́n ó gbọ́n jù wọ́n lọ. The fraudsters thought that elderly man was gullible, but he proved wiser than them.
Most Popular