òjijì

Adjective
ò-ji-jì | | Colloquial |

Definition of òjijì 

1 Kí nǹkan ṣẹlẹ̀ lọ́gán ní àìròtẹ́lẹ̀. sudden f.a.: Àwọn ọ̀dọ́mọdé ìwòyí kò fẹ́ran owó òjijì. Youths of this era do not love sudden wealth.

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 27, 2026 and Submitted on November 16, 2026