1 : Ó túmọ̀ sí kí ènìyàn yí ohùn padà nígbà tó bá ń sọ̀rọ̀ tàbí kéwì nípà lílo àwọn ẹ̀yà ara-ifọ̀ kàn láti gbé ohùn dídùn jáde.: To change voice when speaking or rendering oral traditional poems. f.a.: Mo fẹ́ràn ìwọ́hùn ẹ̀ṣà pípè bàbá Ajóbíewé àti Àṣàbí Ọ̀jẹ̀ Afẹ́napa
Most Popular