1 Ọ̀rọ̀ tàbí ìtọ́ni tí a fún ènìyàn láti fi tó ọ létí nípa ewu, àṣìṣe tàbí ohun búburú tó lè ṣẹlẹ̀. warning, caution f.a.: Bó tilẹ̀ jẹ́ pé bàbá rẹ̀ ti ṣe ìkìlọ̀ fun, kò kọbi ara sí i. Although his father had warned him, he paid no attention.
Most Popular