1 : Eléyǐ ni gbígba àwọn êyàn ṣíṣẹ́ láti bóyá ọwọ́ aládǎni tàbí ọwọ́ ìjọba.: employment, recruitment f.a.: Igbaniṣíṣẹ́ fún àwọn olùkọ́ tuntun ti bẹ̀rẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Recruitment for new teachers has started in Oyo State. f.a.: Igbaniṣíṣẹ́ ilé-iṣẹ́ Dangote tètè bẹ̀rẹ̀ ní ọdún yìí. Dangote's recruitment started early this year
Most Popular