ìbáyému

Noun
ì-bá-yé-mu | | GENERAL |

Definition of ìbáyému 

1 : Ohun tó bá nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ nínú ayé tàbí dọ́gba pẹ̀lú gbogbo ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nínú ayé.: Realism f.a.: Mo fẹ́ràn àwọn ìbáyému inú ìwé Fágúnwá. I like the elements of realism in Fagunwa's books.

Morphology

ìbá-ayé-mu

Gloss

ìbá - align with

ayé - life, world

mu - match

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 18, 2026 and Submitted on November 18, 2026