àkọ́bí

Noun
à-kọ́-bí | | GENERAL |

Definition of àkọ́bí 

1 : ọmọ tí ó jẹ́ pé òun ni ìyá àti bàbá rẹ̀ kọ́ bí.: Firstborn f.a.: Ìfẹ́ ni àkọ́bí nínú àwọn ọmọ mẹ́tẹ̀ta. Ife is the firstborn of the three children.

Morphology

à-kọ́kọ́-bí

Gloss

à - one, someone

kọ́kọ́ - first, before anything else

bí - give birth to

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on November 06, 2026 and Submitted on November 05, 2026