àbọ̀rìṣà

noun
a-bọ̀-rì-ṣà | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of àbọ̀rìṣà 

1 : 1. Ẹni tí ó ń bọ òrìṣà. 2. Ẹni tí àwọn Krìstiẹ́nì gbà pé kìí ṣe ara wọn, tí kìí sì ṣe Mùsùlùmí.:

English Translation

Òrìṣà worshipper.

Morphology

a-bọ-òrìṣà

Gloss

a - someone

bọ - worship

òrìṣà - òrìṣà

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 21 Nov 2019

Most Popular