àáké

noun
à-á-kẹ́ | \ \ | GENERAL/NOT LOCATION SPECIFIC |

Definition of àáké 

1 : Oun ti a fi ń gé igi nínú igbó, tàbí gé igi tí a fẹ́ fi dáná.: Fún mi ní àáké yẹ́n.

English Translation

Axe

Morphology

àá-ké

Gloss

àá - oun ti a fi n

ké - gé (cut)

What Do You Think About This Word?

How could we have illustrated it better?


Updated on 08 Dec 2019 and Submitted on 25 Nov 2019

Most Popular